NOAH EMMANUEL DAMANO |
Bo se wu Edumare ni i sọla. To ba wu ọba oke, o le gbe ọgbọn fun ọmọ kekere, o si tun le gbe laakaye rẹpẹtẹ fun majesin.
NOAH EMMANUEL DAMANO wa lara awon olorin ti n dide bọ eleyii ti Olorun n ti leyin lasiko yii. Eyi lo faa ti mo fi pinnu lati se afihan rẹ fun araye ati igbelaruge orin re tuntun to pe ni IRO NLA.
E pade Damano lori Gbedemukẹ eleyii ti yoo waye lori redio to lagbara julo nile Afirika, www.radiodiaspora.com.ng, lọjọ kejilelogun osu kewaa odun yii (22-10-2016), ni ago mesan-an aaro (9:00am)
Link: https://my.notjustok.com/track/download/id/138647
0 comments:
Post a Comment