Lara idunnu eda laye ni idasi Olorun ọba, aabo, alaafia, owo, ayọ ati ifokanbalẹ. Kosi eyi ninu awon nnkan wonyii ti Olorun ko fi seke Laide Bakare pelu bo se le lọdun lonii ọjọ keje osu kẹwaa odun 2016.
A ba Laide yọ lonii, okan pataki ninu ise tiata ile adulawo, a si gba dura aleekun owo, ayo, alaafia ati emi gigun.
#HappyBirthday #Orekelewa
0 comments:
Post a Comment