Olaniyi Afonja, Sanyeri, ti fi gbogbo awon ololufe re lokan bale nipa sinima tuntun re eleyii to pe ni Omo Alhaja.
Aimoye awon osere ni won ti wa ni ibudo-ere lati ri wi
pe ise naa kesejari. Lara awon osere to wa ni ibudo-ere naa ni Odunlade
Adekola, Afeeze Eniola ati awon mii.
0 comments:
Post a Comment