Smiley face

Adebayo Kode: Ojulowo omoluabi eniyan

Adebayo  Kode.
Orisiirisii ore laani, ojulowo ore ni ko tonkan. Ayederu lo po repete bi yanrin eti okun.

Lara awon omoluabi eniyan ti mo pade ninu igbe-aye mi ni Adebayo omo Kode.

Oni lojo-ibi Bayo ore mi.

Bayo je onisuuru eniyan, laakaye ori re lekenka bee ni ki i gberaga. Bayo feran faaji bee ni ki i seju agbara re lo,ki i si ba omoluabi re je.

Bayo je olokan mimo, ero daradara lo ma n ro nipa ara re ati awon eniyan to sun moo.

Bayo je akikanju, o si korira imele sise lenu ise. Ti eniyan ba mo Bayo ore mi, ko ni fe ba elomii sore mo ayafi Bayo.

Adura mi si Bayo ni opolopo owo, alaafia, idunnu,igbega,ayo, emi-gigun, ilera ati ogbon Oluwa.

Happy Birthday to you my wonderful brother.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment