Smiley face

Bayii ni won se fi ilu ki Funke Akindele kaabo siluu London

Funke Akindele aya Bello ti bale siluu London nibi ti won yoo ti ma se ayeye afihan sinima re tuntun,"Jenifa In London".

Ayeye yii ni yoo ma waye lati ojo kerin si ojo kefa osu kokanla odun yii (4-6/11/16).

Ona ara ni awon ololufee Suliya fi kii kaabo ni papako ofurufu Heathrow pelu bi won se gbelu pade re.

Jenifa naa bere muju loju paali. O gbe owo ijo genge soke, beeni si ni oruka igbeyawo owo re n sana warawara bi ina ilagbede.

Lowo yii ti Jenifa ti wole, o daju wi pe London maa mi titi.




Orisun foto: Teju Ibukunoluwa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment