Smiley face

Madam Aderemi Adeyinka Aromolaran @ 60

Madam Aderemi Aromolaran
Awon Yoruba bo, won ni eniyan taa fun leran ti o tayin, bi won fun eni naa lomo ko ni moore.

Idunnu nla lo subu layo nidile Arabirin Aromolaran nigba ti Madam Aderemi Aromolaran gbe igba ope niwaju Oluwa fun idasi ogota odun (60yrs).

Sebi won ni idunnu lounje agba, inu mama olojo-ibi dun to je wi pe ko le pa idunnu naa mora pelu bi awon omo ati omoomo re se rogbayika bi igba era bo sugar.

Ojo ketadinlogbon osu kewaa ni mama naa le lodun. Sugbon idunnu mi lati ba onire yo.

Adura mi si mama ni alaafia to peye, idunnu, ifokanbale, ilera ati imisi Olorun lati oke wa. Amin

Igab odun, odun kan ni! Ase.

Happy Birthday Ma!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment