Tosin Harmony MrShalom on Radio Diaspora |
Nigba ti mo n mura lati gbalejo Tosin Harmony MrShalom, ẹni to gba ami-ẹyẹ olorin juju to dangajia julọ lẹyin odi, mo ro wi pe o ye kẹẹni
anfaani lati jẹ igbadun orin re ki ọjọ naa to pe.
Awo orin tuntun
Tosin Harmony to n mi gbogbo agbaye lasiko ti a wa yii lo pe akole rẹ ni
"Confirmation".
Eleyii ko si je ko jọ wa loju pupo nigba ti won konfaamu rẹ gege bi "The Most Oustading Juju Artiste in Diaspora 2016 " niluu Canada.
E jẹ igbadun diẹ ninu awon orin naa nibi: Eleyii ko si je ko jọ wa loju pupo nigba ti won konfaamu rẹ gege bi "The Most Oustading Juju Artiste in Diaspora 2016 " niluu Canada.
Track 1 - Bi Mo Se Nlo
Track 2 - Olorun Babalola Ba mi se T'emi
Track 3 - Oti Seese
Track4 - Lelefe - Jolly Time
E tun le kan si Tosin Harmony MrShalom lori FACEBOOK, TWITER ati INSTAGRAM
0 comments:
Post a Comment