Smiley face

Lati bi odun mewaa, Oluwa-si-n-darasi @KunleAfolayan

Awon Yoruba bo,won ni inu eni ki i dun ka pa a mora. Eleyii ni a le fi se apejuwe idunnu Kunle Afolayan, eni ti okiki fiimu re tuntun "CEO" ti kan kaakiri agbaye, pelu bi omo re, Darasimi se pe omo odun mewaa lonii.

Gbogbo wa la ba idile Afolayan yo lonii, a si gbadura wi pe, omo naa yoo diru-digba lase Edua oke. Ase
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment