Lori asemase eleyii to sẹ lati ọwọ Seun Egbegbe lana (22-11-16) pelu bo se n gbiyanju lati ji awon iphone gbe salọ ni agbegbe Ikeja to wa niluu Eko, ni Seun ti ni ko ri bi won se ro o rara.
O ni lotitọ ni oun lọ ra foonu ti won wi. O ni sugbon nigba ti oun ra foonu naa tan , oun sọ fun ẹni ti n ta wi pe ko duro ki oun lo mu owo wa fun un ninu moto lodi keji popona ti oun paaki moto si.

O ni sugbon, o jẹ iyalenu si oun bi omo naa se pariwo ole le oun lori ti gbogbo ero si rọ wa bi ọgbọn, ti gbogbo won si bẹrẹ si ni ko iya fun oun loju paali.
Sugbon sa, omo ti won fi sidi ọja naa so tiẹ, o ni foonu iPhone bi mẹsan-an ni ọdaran afurasi naa loun fẹ ra. O nigba to yẹ ko sanwo ni ọdaran-afurasi naa tun ni ki oun mu ẹlẹẹkẹwa wa.

O ni ki oun to wọle jade, Seun Ẹgbẹgbẹ ti poora bi iso pẹlu awon foonu bi mesan-an ti oun ti ko fun. O ni koda, moto rẹ ti gbera bi aja-4 ki oun to pariwo soke.
"Ti ko ba se wi pe ikolukọgba to ma n waye ninu Computer Village ni, Seun Egbegbe ko ba ji awon foonu naa salo patapata." - omo ti won fi sọgba
Siwaju sii, ile ise olopaa ipinle Eko ti jẹri si isẹlẹ naa. Won ni looto ni awon eniyan mu ọdara-afurasi naa ti oruko re n je Seun Egbegbe sugbon ohun ti won wi ni wi pe, iwadii si n tesiwaju lori mata naa.

0 comments:
Post a Comment