Titi di akoko yii, a ko ti le sọ boya asasi ni tabi eedi, sugbon ohun ti a gbọ ni wi pe, Seun Egbegbe, to jẹ ọkọ Toyin Aimakhu nigba kan ri, ni won mu gẹgẹ bi ole laarọ yii laaarin ọja Computer Village to wa niluu Eko.
Lara awon foonu to ji ko ni won ti ri iPhone 7 meji pelu
awon iPhone 6 bi meloo kan eleyii ti apapọ owo re n lo si bi milionu
meji o le.
Kini Seun Egbegbe fẹ fi aduru foonu yii se? Seun Egbegbe ti emi mọ ki i se ẹni toju pọn, ki lo wa le fa iru iwa bayiii?
Ju gbogbo rẹ lọ, ẹ jẹ ka tunbọ tẹtileko fun akotun iroyin naa. Ko ma lo je wi pe fiimu la n wo.
E tun le ka nipa Seun Egbegbe NIBI
0 comments:
Post a Comment