Isẹ ewi je
isẹ ẹ̀mí, ímísí eleyii to tayọ ọgbọn ori lasan ati lakaaye. Awon kan tilẹ se
apejuwe ojulowo ewi gẹgẹ bi isura iyebiye. Boya eyi lo mu Olanrewaju Adepoju
salaye ninu ewi re kan wi pe,
"akewi ti won ba ja lólè ise ọpọlọ ko yato sẹni tọmọku lọwọ rẹ".Eleyii se apẹrẹ bi ojulowo ewi se tẹwọn to. Lara ọna ti awon ojulowo akawi maa n gba lo ise won ni lati ta awon eniyan jigiri, mu won ronujinlẹ, lati mu won lokan le ati lati fun won ni ireti nla.
Tuntun ni eleyii to pe ni TURNING POINT, o ya e je ka lọ kofa ise ọpọlọ gidi.
0 comments:
Post a Comment