Smiley face

"Mi o le gbe ni Aso Rock l'Abuja"- Yanju Adegboyega

Ogbeni Yanju Adegboyega je okan lara awon oga agba ileese akoroyin Alariya Oodua. Ohun ti okunrin naa gbe jade lori Facebook re ni yii:

"Walaaahi!

Ti won ba fun mi ni yara kan nile ijoba orileede yii, mi o le gbaa.

Ironsi atiyawo re lo jo lo sibe, iyawo re nikan lo pada bo.

Muritala atiyawo re lo lo sibe, iyawo re nikan lo pada bo.

Abacha ati Maryam lo lo sibe, Maryam nikan lo pada bo.

Obasanjo ati Stella lo lo sibe (lasiko isejoba alagbada re), Obasanjo nikan lo pada.

Yar'Adua ati Turai lo jo lo sibe, Turai nikan lo pada.

Buhari ati Aisha lo jo lo sibe......
Hnnnmmm! Oro bale, a ditan bi oruko aburo mi kan ni Ogbomoso.'

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment