Gege bi igbejo esun ole ti won fi kan Ogbeni Seun Egbegbe nipa foonu ti won lo ji ni agbegbe Ikeja ninu odun 2016. Oni, Feb 8, lo ye ki ejo naa tesiwaju. Sugbon ohun ti a gbo bayii ni wi pe, won ti sun ejo naa di osu kerin odun 2017.
Nipa owo ilu okeere awon Gambari ti ololufe Toyin Aimakhu nigba kan ri fe fi agbari jagba, ojo Jimoh ti n bo yii [19-02-2017] ni won yoo ma gbe keesi re dide niwaju adajo.
Wayio, awon agbofinro ile Naijiria olominira so wi pe, odo awon ni Ogbeni Egbegbe si wa nibi ti awon fi ha legbe kan ninu gbaga pelu awon eniyan bi e wa.
0 comments:
Post a Comment