Awon omobirin yii ni won ri nile ijo kan ni ipinle Eko.
Ibaje ti dewa lawujo wa
Ni aye igba kan, ise itiju ni ise asewo. Laye ode oni, asewo ti di oun ti awon obirin fi n yangan kaakiri. Oju ki i ti won mo, ibaje ti dewa a ko fura.
Awon omobirin yii ni won ri nile ijo kan ni ipinle Eko.
0 comments:
Post a Comment