Smiley face

Ise asewo ti dohun amuyangan lawujo wa?

Opolopo awon omoge iwoyii lo ti gbe igba asewo sise bi ise gidi ti n pawo wole.

Ohun to ba ni lokan je julo ko ju wi pe, oju ki i ti won lati se afihan ara won gege bi onise nabi.

Se eto oro aje Naijiria to denukole lo faa ni abi olaju?

Ni aye igba kan, ise asewo ki i se ohun ti won mu yangan. Sugbon ni bayii, o ti di ohun ti won pate re ni gbangba.

Se bi o se ma ri lo ni yii?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment