To ba je t'IFA gidi to je ojulowo Ifa, taani ko mo Araba Ifayemi Elebuibon?
To ba je asayan ewi to mogbon dani, emi mo Olanrewaju Adepoju, agbalagba l'Olatunbosun Oladapo ninu ise opolo to fakiki.
Ta ba n so nipa oniroyin to gbamuse, Wale Ojo-Lanre ti goke agba. Oniroyin irin-ajo afe bi Alarinka Agbaye ko meji lojude.
Ogbon ori lo fi n sise opolo, laakaye ni fi n tayo.
Lotito, eni mi kukute ara re lo mi.
E wa wo Wale bo se n jaye lori omi bi Oba Lamidi. Yeepa!

0 comments:
Post a Comment