Omokunrin to so ara di omobrin osan gangan, Bobrisky ti so wi pe oun le paayan nitori Wizkid. Igba akoko ko ni yii ti Bobrisky ti n fi ife han si Wizkid gege bi eni to wuu lati je ololufe re. Sugbon ife gbigbona oteyi tun ga.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
5/01/2017 08:50:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment