Eto ti ale ana yii ni i se iso oru ojo kerindinlogun (16). Aimoye eri ise iyanu ni awon eniyan si ti fi n ranse pade kaakiri orileede Nigeria ti won ti wo eto naa.
Opin osu kefa odun yii ni eto naa yo pari, e le dara po mo eto naa ni deede ago mejila oru si ago kan oru akoko ago ile Naijiria.
Hallelujah!
0 comments:
Post a Comment