Smiley face

Dukia MKO: Awon ebi setan lati dide ogun si Kola Abiola

Okan ninu awon omo oloogbe MKO Abiola, Abdulmumin Abiola ti bere lati gbogun ti egbon won, Kola Abiola latari bi o se jegaba lori dukia baba won.

"Emi ki i se omo agbojulogun, sugbon o dabi eni wi pe o kudiekaato bi egbon wa agba se n dari ohun gbogbo nibi taa ti ni awon omo ti won je okunrin ati obirin to logbon lori sugbon ti enikan soso si daya bo gbogbo dukia patapata"- Abdulmumin.

Abdulmumin to je omo Kudirat lo ni bi odun bi mejidinlogun leyin iku baba won ni awon fi ni suuru fun booda Kola sugbon o dabi wi pe won ko leto kankan fun wa. To ba je wi pe won ma pin ogun ni, ki won pin ki onikaluku gba tie.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment