Smiley face

Bayii ni oruko awon AWORI se jeyo gege bi omo Oduduwa

Awon Yoruba bo, won ni tewe ba pe lara ose, dandan ni ko dose. Awon Awori lo lEko nitori ojo ti pe ti won ti mule nibe.

Eleyii lo faa ti awon naa fi darapo mo ijoba ipinle Eko lati se ajoyo aadota (50) odun ti won da ipinle Eko sile.

Odun wo ni awon Awori wo ilu Eko?
Bawo ni won se de be?
Oruko won ti won je: "AWORI", ki lo bi oruko naa?

Alaye wa ninu linki isale yii
https://youtu.be/WnwigZKXZuw

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment