Smiley face

"O ti di igba karun-un ti awon ika eniyan kede iku mi"- Odunlade Adekola

Awon Yoruba ni tewure ba boju weyin, yoo fepe felepe. A ti wi pe, ti a ba n le were laipada, to ba ya were yoo yiju pada sini.

Osere tiata ile Naijiria, Odunlade Adekola ti fepe ranse si awon ti won kede iku re lai ti ku.

Osere naa ni eleyii ni igba karun-un ti awon eniyan ibi naa yoo ma kede iru nnkan buruku bee.

Nikete ti osere yii fohun jade ni awon ololufe re kaakiri agbaye si ti bere si ni rojo adura fun un wi pe ko ni ku, sugbon yoo ye ni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment