Smiley face

Eyin te e ma lo sile asewo e wa gbo o

E sora o!

Abajade iwadii ti awon kan se nipa awon ile asewo to wa niluu Eko ti fidi re mule wi pe, iye awon to ni kokoro HIV ti lo soke sii ni ipinle Eko. Won ni pupu ninu awon asewo yii ni won lo ayederu kondoomu tabi eyi ti ojo ti lo lori re (expired). Eleyii si ti fa akoba nla fun won ati awon onibara won.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment