Smiley face

Ole wonu soosi lo sise dudu

Won ti mu niluu Bayelsa, won ko pankere boo nidi waiwai, won tun wa ja sihoho omoluabi. Kini maanu naa se? Kilosele gan-angan? Won lo n gbiyanju lati ji keyboard church kan ma ni o. Ni awon boys adugbo ba ni ki maanu ole naa fi owo ara re login si ajekuniya.com. Nigba to login tan, lo ba bere si ni download igbati, igbarun, gbekunmi, iforun, shiko, noku, boju-alata abbl.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment