Smiley face

Kini Dino Melaye se ti won fi pe lomo ale leemeta?

Lojo kejila osu kefa odun yii ni awon agbebon kan digbolu Ogbeni Dino Melaye ni ilu Lokoja nibi to ti n ba awon alatileyin re soro. Isele yii, eleyii to waye niwaju ile eko gbogbo-nise ipinle Kogi to wa ni Lokaja, ni won ti pa awon eniyan bi meji ti won je ololufe Dino. Sugbon nipa ti Dino, abere lo ki ona okun to di.

Leyin isele yii ni Senato Melaye lo sori ero twitter lati dupe fun Olorun fun oko ayeta re to koyo lowo iku ojiji naa.

Sugbon esi to gba pada panilerin pupo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment