Naijiria ti pada si ese aaro, won ti n kosu lo ta loke okun Ola Daviva 6/30/2017 09:29:00 pm Ise Ogbin Edit Ile Naijiria ti bere si ni ko nnkan ogbin lo ta loke okun bayii pelu bi won se bere pelu isu tita si oke okun. Awon onwoye eto oro aje ni eyi dun un gbo seti nitori epo robi ti gbogbo wa gbojule ti n ja wale laarin oja agbaye Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Naijiria ti pada si ese aaro, won ti n kosu lo ta loke okun Reviewed by Ola Daviva on 6/30/2017 09:29:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment