Smiley face

Baalu awon omo ologun ja niluu Amerika

Awon eniyan bi merindinlogun (16) ti koja lo sorun bayii niluu Amerika latari baalu awon omo ologun ile Amerika to jalule ni Mississippi. Isele to waye lojo Aje yii naa lo seku pa gbogbo awon omo ogun merindinlogun ti wa ninu baalu naa lai si enikeni ninu won to moribo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment