Dino Melaye ti wogbon da, o ti lo gba iwe ni kootu fun INEC
Senator Dino Melaye ti lo gba iwe ikanilowoko lati ile ejo fun ajo INEC lati si won lowo ninu akitiyan a ti da Dino Malaye pada sile lati ile igbimo asofin. Melaye ni awon eniyan ekun ti n soju fun ni Ipinle Kogi kowe ranse si INEC wi pe, awon ko fe e mo gege bi asoju won.
0 comments:
Post a Comment