Fun anfaani eyin ti e ko ti ka THE HISTORY OF THE YORUBAS lati owo Rev Samuel Johnson, e le download e bayii.
Ori PDF lo wa, ko si ni na yin ju 32mb lo pere lati download iwe pataki yii.
E gba mi laaye lati se afikun kekere yii:
Gege bi oro okunrin onwoye kan, o ni ona to ya ju lati fi nnkan (ogbon, imo tabi oye) pamo fun awon eniyan dudu ni nipa sise akosile re sinu iwe.
Ohun to mu so bayii ni wi pe, awon eniyan dudu won ki i kawe rara.
E je ki n dake nibi, LINK naa wa nisale.
DOWNLOAD: https://t.co/UwHL87f8ah
0 comments:
Post a Comment