Aimoye dukia lo ti sofo bayii nigba ti awon kan ko tile le so boya awon eniyan ti won ko ri ti bomi lo abi won wa nibi kan ti won sapa
Ogun (20) eniyan ti bomi lo ni Suleja
Awon eniyan bi ogun (20) ni omi ti gbe lo bayii ni Suleja to wa nipinle Niger nibi ti agbara omiyale ti gbe n se jamba.
0 comments:
Post a Comment