Smiley face

Naija e maa jo, e maa yo - Aisha Buhari lo so bee

"Eyin omo Naija e maa jo, e maa yo, aare Muhammad Buhari ti n gbadun, ko si ni pe pada wale." Aisha Buhari, aya Sai Baba lo fohun ranse bee lati ilu Oba Biritiko nibi to ti lo se abewo si oko re ti n gba itoju lowo niluu London.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment