Aimoye gbon-mi-si-omi-o-to, wahala, gobe, surutu, ija, ogun, ote, lo ti n waye laaarin awon idile ti won ti n joba eleyii ti aimoye rere run sibe.
Sugbon a dupe, alaafia ti n joba. Ademola Folakanmi ni Alado asiko yii. Ki oba pe bi pepe ti n pe. Ki esin Oba jeko pe. Ase.
0 comments:
Post a Comment