Alaye naa wa ninu link isale yii
Ohun meje ni igbe aye baba mi, Fela Anikulapo-Kuti, ko fi wu mi- Femi Kuti
Femi Kuti, omo oloogbe Fela Anikulapo-Kuti, ti se alaye fun mi idi pataki ti ko fi wu u lati gbe iru igbe aye baba re. Yato si eleyii, o se alaye bi baba re se je ABAMI EDA looto, eleyii to rekoja afenuje oruko lasan.
0 comments:
Post a Comment