Smiley face

Wole Soyinka @ 83: Akanda eda onirun funfun

Akinwándé Oluwo̩lé Babátúndé S̩óyinká ti gbogbo eniyan mo si Wole Soyinka ti pe omo odun metalelogorin bayii (83).

Ojo ketala osu keje odun 1934 ni won bi onkowe yii, oun kan naa si n omo Naijiria akoko ti yoo gba ami-eye agbaye ninu ise litiraso ti a mo si Nobel Prize in Literature eleyii ti won gbe fun un lodun 1986.

A fi asiko ki Ojogbon ku oriire odun tuntun to baa laye. Igba odun, odun kan ni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment