Odidi ebi kan yii ti awon Badoo parun ni ojo kokandilogbon osu kefa (29th June) odun yii ni won ti fi eto isinku won si ojo kerinla osu keje (14th July) odun yii niluu Eko.
Akanse eto orin idaro awon oloogbe ni yoo waye ni ojo ketala osu keje saaju eto isinku won.
Ki Edumare ba wa te won si afefe rere.
0 comments:
Post a Comment