Smiley face

Oruka ti n dena kokoro HIV ti jade niluu Amerika

Awon ojogbon onimo sayensi kan niluu Amerika ti kede oruka ajebiidan ti won fi rubber se eleyii to le dena koko HIV fun awon odobirin ilu naa.

Oruka naa wa fun awon odobirin laaarin odun 15yrs si 24yrs ti won feran "ogede agbagba" ni jije.

Oju ara ni won yoo ti oruka naa bo eleyii ti ko si ni di won lowo nigba ti won ba n jo "skelewu" lowo.

Ki won to kede oruka yii ni won ti se ayewo re eleyii ti won ni ise re pegede.

Sugbon sa, awon onise ilera agbaye so wi pe, ona to si pegede julo lati fun ni idaniloju lati dena arun naa ni yiyeba fun ibalopo eleyii to le fun ni igbelewon 100% idaniloju.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment