Baasoro Ile Yoruba, Alh Kola Olootu |
Ninu awọn eto Kola Olootu, Oselenkejọ, Oloye yii ti fi igba kan salaye awon nnkan ara-ọtọ to mu awon olorin gbayi lọwọ rẹ. Awon nnkan ti Olootu si se apẹẹrẹ rẹ yii la gba wi pe o mu awon olorin naa tayọ.
Sugbon taani yoo so nipa Kola Olootu?
Lara awon nnkan to mu Kola Olootu gbayii lọwọ mi ko ju ọgbọn atinuda rẹ to tayọ, arogun ati arojinle rẹ si wayami pupọ.
Ninu isẹ amuludun, kosi bi eniyan ti wulẹ ko lẹbun to, bi ko ba le sẹda ohun tuntun nigba gbogbo, awon eniyan ko ni pe pada leyin rẹ.
Otunba Kola Olootu ki i ye jọ awon ololufẹ rẹ loju nipa sise awon nnkan ti ko sẹleri lẹka igbohunsafẹfẹ ori redio.
Mo kan ni ki n se afihan diẹ lara awon eto Baasọrọ ni akoko ti Omo Adabanija wa ni orileede Saudi Arabia.
E ku ikalẹ!

0 comments:
Post a Comment