Smiley face

Atiku ti pada leyin Tinubu ati egbe APC

Atiku ti kede wi pe oun ti kuro ninu egbe APC. Bi o tile je wi pe ko ti so pato nipa egbe oselu to fe darapo mo. Sibesibe, igbagbo ati aheso awon eniyan ni wi pe, o seese ko je egbe alaburada ni Turaki Adamawa fe ba se.

Gege bi alaye awon onwoye oro oselu ile adulawo, won ni ohun gbogbo ni oko Titilayo n se lati di "Oluomo" lodun 2019 nitori o dabi eni wi pe anfaani kan soso to kun fun un ni yii lagbo oselu.

Atiku Abubakar, eni ti Ooni Oba Okunade Sijuwade fi je Aare Adimula orisun ile Yoruba la gbo wi pe, o gbe igbese tuntun yii lati fi egbe APC sile latari wi pe ko si idaniloju fun un wi pe egbe onigbale yoo fa kale gege bi asoju oludije aare odun 2019.

Oro oselu Nigeria, ilu awon eniyan rere, ni   a le fi we ojo to n ro ti ko ti da, oba oke nikan lo moye eni to ku ti yoo pa.

E ku ikale!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment