Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, pé ẹni ọdún márùn-ún-le-ni-aadota (55) lojo Isegun to koja yii, 19/12/17.
Aimoye awon ènìyàn ní won ṣe àlàyé Bukola Saraki gege bi oloselu ńlá eleyii ti ko se fọwọ́ ro seyin lagbo oselu òde òní.
Aimoye akitiyan ni àwon alátakò rẹ gbiyanju lati ri wí pé kò rí aare ile igbimo je, ṣùgbọ́n leyinoreyin, oko Toyin lo borí wob pata.
Eleyii fi hàn gege bi akíkanjú. Saraki a ma wo bí ẹni wí pé kò mọ ohunkóhun, ṣùgbọ́n ọgbọ́n inú pé egbèje.
#HappyBirthday Igba ọdún, ọdún kan ni.
0 comments:
Post a Comment