Smiley face

Atiku Abubakar níbi eto ìsìnkú Alax Ekwueme nílùú Abuja

Atiku Abubakar pada àwọn olóṣèlú ńlá níbi eto ìsìnkú ìgbà kejì Aare nígbà kan rí, Alex Ekwueme, eléyìí to wáyé nílùú Abuja. Atiku to tí fi ìgbà kan je ìgbà kejì aare ni òun náà ń múra báyìí láti dù ipo aare lodun 2019.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment