Smiley face

Ọmọge onídòdò tí patẹ ọjà fáyé

Ìṣe aṣẹ́wó kii se ohun ìtìjú mọ báyìí. Àwọn tí wọn ṣe gba a gẹ́gẹ́ bí ìṣe ajé ni, lára ohun tí olaju mú wọlé nù un. Ọkàn nínú àwọn ọmọge Lekki ni yìí, eléyìí to tí rẹdi fún ìṣe ajé tí ẹ.

To ba ti setan, orí ayélujára ni yóò ti patẹ ipolówó níbi tí àwọn onibara yóò sì ti má bá nája rẹ wàrà wàrà. Àwọn kan sọ wí pé olaju lo fà eléyìí nígbà tí àwọn kan sọ wí pé "poverty" ìṣẹ́ to pọ láwùjo wá lọ ṣokùnfà àwọn ìwà yìí.

Kini èrò tí yín?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment