Káàkiri àgbáyé ni àwọn tí soro Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi adari ìjọ Love of Christ Generation C&S to wá Clapham ni ilu London gege ojisẹ Ọlọ́run onínú irẹ, to sì ń lo gbogbo agbára, ọlá àti imo láti mú igbe ayé àwọn ènìyàn dára sí.
E ba wa kí wọn wí pé wọn kú iṣẹ́ Olúwa
0 comments:
Post a Comment