Smiley face

Ìwúre fún àwọn agunbaniro tí wọ́n fe lọ sókè oya

Fún àwọn tí wọn gbaradi láti lọ fún  agunbaniro ni akoko yii, mo gbàdúrà wí pé ààbò Eledumare tó dájú yóò wà lórí wọn. Àmìn #CorperSneh

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment