Ni ìbẹ̀rẹ̀ ọdún yìí, mo ti bá Ọlọ́run dá majẹmu wí pé mi ó ni sofofo mọ.
Bákan náà, mi ó ní dá sí ọ̀rọ̀ oloro tí ó kàn mí, má feesi bisineesi mi lodun 2018.
Mo ń gbìyànjú ó, ṣùgbọ́n kí Olúwa túbọ̀ ran mi lọ́wọ́. Kò easy.
Ǹjẹ́ èyín tí gbọ? Mercy Aigbe tí ọkọ rẹ fe lu pá lodun 2017, tó jẹ́ wí pé òun gan-an fi ọlọ́pàá gbé ọkọ rẹ, Lanre Gentry, ti wọn si ti bàbà ọmọ rẹ mọ́lẹ̀ ni agọ olopaa fún àìmọye ọjọ́.
Se ẹyin lè biliifu wí pé, ọmọbìnrin náà tí ń fi ọgbọ́n kò ẹrú rẹ padà sílè ọkọ rẹ báyìí?
0 comments:
Post a Comment