Smiley face

Oko Victoria tí fún ìyá Victoria loyun: Ọ̀rọ̀ Radarada

VICTORIA :Ọkọ mi fún ìyá mi lóyún. Kini kí n ṣe?

John: Ìyá ìyàwó mi lọ ń gbé sún mọ́ mi. Ẹ mi náà bá ko bajinatu boo lábẹ́. Mí ó mọ wí pé yóò doyun ìṣe èṣù ni. Ẹ dárí jin mi.

Iya ìyàwó: Mo ní kí n yọ ṣe lẹẹkan péré ni.   Sugbon mí ò mọ bó ṣe di joojumọ. Mo setan láti seyun ẹsin náà. Ẹ forí jí mi.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment