Arábìnrin kan tó fẹ́ tirafu pelu ẹyẹ ọkin ni wọn ti dapada nígbà tó kú kò gbese wọnú baalu ni orileede America 🇺🇸.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ọmọbìnrin náà ra ticket fún ẹyẹ rẹ láti jókòó nínú baalu lọtọ. Sibẹsibẹ, àwọn aláṣẹ Newark Liberty International Airport to wá ní New Jersey so wí pé, kò bá ìlànà àwọn mu.
Ọmọbìnrin náà ṣe àlàyé wí pé, ọrẹ òun ni ẹyẹ náà àti wí pé, ó má ń fún òun ní ìtura. Gbogbo atotonu rẹ, pagbo lo jásí.
Ọmọbìnrin yìí dúró síbè, bí alẹ kan àárọ̀ kan. Ó un wo bí aláàánú Samáríà, òun àti ẹyẹ rẹ. Ẹnikẹ́ni kò dá sí wọn mọ. Ìgbà to yà ni baalu fò, baalu wá lókè, oun àti ẹyẹ rẹ sì wá nisalẹ. Ayé lè ó!
Fún ipolowo àti ikede
+2348032394964
yemoford@gmail.com
0 comments:
Post a Comment