Smiley face

Wọn kan Obasanjo labuku nla

Won tí ń kan Obasanjo labuku látàrí àjọ to dá silẹ eléyìí to tí ń jọ bí ẹgbẹ́ oselu  lójú àwọn ènìyàn. Pabambari ibẹ ni àwọn  tí Baba Iyabo ko sódì, wọn ní jaguda, ole, gbewiri, barao, tiifu ni gbogbo wọn.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment