Smiley face

Oonirinsa níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Asiwaju Bola Tinubu

Ọ̀rọ̀pọ̀tọyùn ọba àwọn ìlékè, idẹ lọ́wọ́ idẹ léṣẹ̀, adé funfun lẹlẹ, ọ̀pá àṣẹ ń sáná yinginyingin, bàtà Adeyeye nkọ?  Ọba alasọ funfun ọmọ Ogunwusi. Ọba to ja bí Ojaja ò sì. Wó Adimula bo se n gbẹsẹ bi oosa. To ba rìn, a yánpá fanda bí ẹni sakọ. Bẹ́ẹ̀ Adeyeye ó sakọ, Edumare lọ dá pelu ògo. Ó naro ó dúró wamuwamu. Adọgbadelẹ arẹwà ọba. A ṣe ènìyàn lè wá láyé lai lábùkù... Arole Odùduwà ń bọ, ẹ bìlà 😂

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment