Smiley face

Sí Abiodun Olanrewaju ọ̀rẹ́ mi

Olanrewaju kú Ojúmọ́.
Má gbàgbé ọ̀rọ̀ tí mo bọ́ ọ sọ lóru àná. 
Jẹ ọlọ́gbọ́n, ó ti kúrò lọmọde. 
Bí ẹnikẹ́ni bá ṣẹ ọ má bínú tán. 
Má finú tán ẹni i múnú rẹ dùn lónìí. 
Ìdí ni wí pé ènìyàn má ń yí. 
Ẹni ire a má di búburú. 
Ẹni burúkú a sì ma padà dire nígbà míì. Ènìyàn ni ènìyàn, Allah nìkan ló kógo já. Karimu má gbàgbé ọ̀rọ̀ mi, jẹ ọlọ́gbọ́n. Ire 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment