"Bukola Sàràkí ni bàbá ìsàlẹ̀ wa" Awọn adigunjale banki Ọfa tí jẹwọ Olayemi Oniroyin 6/03/2018 06:54:00 pm Add Comment Edit Ni olu ileesẹ ọlọ́pàá nílùú Abuja, wọn ti ṣe àfihàn àwọn afurasi adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye nílùú Offa, Ìpínlẹ̀ Kwara. Àwọn afurasi a... Read More
Dangote kò àádọ́jọ (150) ọkọ̀ kalẹ fún àwon ọlọ́pàá Olayemi Oniroyin 5/31/2018 10:06:00 pm Add Comment Edit Dangote Foundation eléyìí to jẹ àjọ tí Alh Aliko Dangote gbé kalẹ láti lè fi má rán àwùjọ lọ́wọ́ tí pèsè àádọ́jọ (150) ọkọ fún ilé ìṣe ọlọ́p... Read More
"Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi, bákan náà lo bá mi ni ajosepo fún ọdún mẹ́rin" Olayemi Oniroyin 5/25/2018 06:23:00 am Add Comment Edit "Bàbá mi má ń fẹnu fà ọyàn mi, bákan náà lo bá mi ni ajosepo fún ọdún mẹ́rin" Ọmọbìnrin ẹni ọdún méjìdínlógún (18) tí bàbá rẹ̀ n ... Read More
Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LASU Olayemi Oniroyin 5/24/2018 06:06:00 pm Add Comment Edit Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá, Iba Gani Abiodun Ige Adams náà tí padà kàwé gboyè ni ile ẹ̀kọ́ Yunifásítì. Ṣebi àwọn Yorùbá lóní imọ kò pín s... Read More
Meji nínú àwọn olè Ofa tí de òpin ìrìn àjò wọn Olayemi Oniroyin 5/22/2018 10:17:00 am Add Comment Edit Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà tí tẹ àwọn méjì míì tí wọn wá lára àwọn adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye ènìyàn l'Ofa. Ohun tí a gbọ ni wí p... Read More