Ọkàn nínú àwọn olólùfẹ́ ẹgbẹ́ PDP, Demola Olanrewaju, tí fepe ranse si àwọn ololufe Buhari ti won ma takoo ni joojumo.
Read More
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Buhari@75 Àwọn gómìnà tí wọ́n ko rí owó oṣù òṣìṣẹ́ san náà fẹ̀yìn síta
Àfikún àwọn fọ́tò láti bi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Buhari @75. Àwon gómìnà tí wọ́n kò rí owó oṣù àwọn òṣìṣẹ́ san náà lọ jẹ iresi àti ọtí wáìnì. ...
Read More

Buhari@75:Ti won ba gbe ère Abdulsalam Abubakar kò ti poju fún ipa to ko lórí oro Nàìjíríà
Aare ológun ìgbà kan, Abdulsalam Abubakar, naa se abewo si Aare Muhammadu Buhari niluu Abuja. Ṣùgbọ́n ká má paro, Abdulsalam je okan lara a...
Read More

"Olùgbàlà"tí sa lọ: Lẹ́ta sì àwọn ọmọ Nàìjíríà
Kí n má parọ́ àsìkò kò ti to fún Nàìjíríà láti bọ lọ́wọ́ àwọn olóṣèlú amúnisìn. Bi o tilẹ̀ jẹ́ wí pé òye àwọn ènìyàn tí ń lá ju ti ateyinwa ...
Read More

Ẹbọ kànkà méje tí ń kagún láyà tí Buhari gbọ́dọ̀ ru kí ètò ìdìbò ọdún 2019 tó wọlé dé
Pupo àwọn ọmọ Nàìjíríà si ni ìgbàgbọ́ nínú Buhari. Ṣùgbọ́n títí di àkókò wo ni awon ènìyàn yóò lè mú ara ró fún Buhari? Atiku Abubakar tí d...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)